Efe 6:1-3

Efe 6:1-3 YBCV

ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́. Bọ̀wọ fun baba ati iya rẹ (eyi ti iṣe ofin ikini pẹlu ileri), Ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le wà pẹ li aiye.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Efe 6:1-3

Efe 6:1-3 - ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́.
Bọ̀wọ fun baba ati iya rẹ (eyi ti iṣe ofin ikini pẹlu ileri),
Ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le wà pẹ li aiye.Efe 6:1-3 - ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́.
Bọ̀wọ fun baba ati iya rẹ (eyi ti iṣe ofin ikini pẹlu ileri),
Ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le wà pẹ li aiye.