Oni 8:5-7

Oni 8:5-7 YBCV

Ẹnikẹni ti o pa ofin mọ́ kì yio mọ̀ ohun buburu: aiya ọlọgbọ́n enia si mọ̀ ìgba ati àṣa. Nitoripe ohun gbogbo ti o wuni ni ìgba ati àṣa wà fun, nitorina òṣi enia pọ̀ si ori ara rẹ̀. Nitoriti kò mọ̀ ohun ti mbọ̀: tali o si le wi fun u bi yio ti ri?