Oni 4:9-10

Oni 4:9-10 YBCV

Ẹni meji san jù ẹnikan; nitori nwọn ni ère rere fun lãla wọn. Nitoripe bi nwọn ba ṣubu, ẹnikini yio gbe ọ̀gba rẹ̀ dide: ṣugbọn egbe ni fun ẹniti o ṣe on nikan nigbati o ba ṣubu; ti kò li ẹlomiran ti yio gbé e dide.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún Oni 4:9-10

Oni 4:9-10 - Ẹni meji san jù ẹnikan; nitori nwọn ni ère rere fun lãla wọn.
Nitoripe bi nwọn ba ṣubu, ẹnikini yio gbe ọ̀gba rẹ̀ dide: ṣugbọn egbe ni fun ẹniti o ṣe on nikan nigbati o ba ṣubu; ti kò li ẹlomiran ti yio gbé e dide.Oni 4:9-10 - Ẹni meji san jù ẹnikan; nitori nwọn ni ère rere fun lãla wọn.
Nitoripe bi nwọn ba ṣubu, ẹnikini yio gbe ọ̀gba rẹ̀ dide: ṣugbọn egbe ni fun ẹniti o ṣe on nikan nigbati o ba ṣubu; ti kò li ẹlomiran ti yio gbé e dide.