Oni 1:2-3

Oni 1:2-3 YBCV

Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn?