Oni 1:14-15

Oni 1:14-15 YBCV

Mo ti ri iṣẹ gbogbo ti a nṣe labẹ õrùn; si kiyesi i, asan ni gbogbo rẹ̀ ati imulẹmofo. Eyi ti o wọ́, a kò le mu u tọ́: ati iye àbuku, a kò le kà a.