Oni 1:1-3

Oni 1:1-3 YBCV

Ọ̀RỌ oniwasu, ọmọ Dafidi, ti o jọba ni Jerusalemu. Asan inu asan, oniwasu na wipe, asan inu asan; gbogbo rẹ̀ asan ni! Ere kili enia jẹ ninu gbogbo lãla rẹ̀ ti o ṣe labẹ õrùn?