Deu 11:26-27

Deu 11:26-27 YBCV

Wò o, emi fi ibukún ati egún siwaju nyin li oni; Ibukún, bi ẹnyin ba gbà ofin OLUWA Ọlọrun nyin gbọ́, ti mo palaṣẹ fun nyin li oni