Dan 7:15-17

Dan 7:15-17 YBCV

Ẹmi emi Danieli si rẹwẹsi ninu ara mi, iran ori mi si mu mi dãmu. Mo sunmọ ọkan ninu awọn ti o duro lapakan, mo si bi i lere otitọ gbogbo nkan wọnyi. Bẹ̃li o sọ fun mi, o si fi itumọ nkan wọnyi hàn fun mi. Awọn ẹranko nla wọnyi, ti o jẹ mẹrin, li awọn ọba mẹrin ti yio dide li aiye.