Iṣe Apo 3:15

Iṣe Apo 3:15 YBCV

Ẹnyin si pa Olupilẹṣẹ ìye, ẹniti Ọlọrun si ti ji dide kuro ninu okú; ẹlẹri eyiti awa nṣe.