Iṣe Apo 13:48-49

Iṣe Apo 13:48-49 YBCV

Nigbati awọn Keferi si gbọ́ eyi, nwọn yọ̀, nwọn si yìn ọ̀rọ Ọlọrun logo: gbogbo awọn ti a yàn si ìye ainipẹkun si gbagbọ́. A si tàn ọ̀rọ Oluwa ka gbogbo ẹkùn na.