Iṣe Apo 12:23

Iṣe Apo 12:23 YBCV

Lojukanna angẹli Oluwa lù u, nitoriti kò fi ogo fun Ọlọrun: idin si jẹ ẹ, o si kú.