Iṣe Apo 11:24

Iṣe Apo 11:24 YBCV

Nitori on jẹ enia rere, o si kún fun Ẹmí Mimọ́, ati fun igbagbọ́: enia pipọ li a si kà kún Oluwa.