Iṣe Apo 1:26

Iṣe Apo 1:26 YBCV

Nwọn si dìbo fun wọn; ìbo si mu Mattia; a si kà a mọ awọn aposteli mọkanla.