II. Tim 2:4-6

II. Tim 2:4-6 YBCV

Kò si ẹniti njàgun ti ifi ohun aiye yi dí ara rẹ̀ lọwọ, ki o le mu inu ẹniti o yàn a li ọmọ-ogun dùn. Bi ẹnikẹni ba si njà, a kì dé e li ade, bikoṣepe o ba jà li aiṣe erú. Àgbẹ ti o nṣe lãlã li o ni lati kọ́ mu ninu eso wọnni.