II. Sam 11:26-27

II. Sam 11:26-27 YBCV

Nigbati aya Uria si gbọ́ pe Uria ọkọ rẹ̀ kú, o si gbawẹ̀ nitori ọkọ rẹ̀. Nigbati awẹ̀ na si kọja tan, Dafidi si ranṣẹ, o si mu u wá si ile rẹ̀, on si wa di aya rẹ̀, o si bi ọmọkunrin kan fun u. Ṣugbọn nkan na ti Dafidi ṣe buru niwaju Oluwa.