II. Kor 3:3-4

II. Kor 3:3-4 YBCV

Bi a ti fi nyin hàn pe, iwe Kristi ni nyin, ti a nṣe iranṣẹ fun, kì iṣe eyiti a fi tadawa kọ, bikoṣe Ẹmí Ọlọrun alãye; kì iṣe ninu tabili okuta, bikoṣe ninu tabili ọkàn ẹran. Irú igbẹkẹle yi li awa si ni nipa Kristi sọdọ Ọlọrun