II. Kor 3:16-17

II. Kor 3:16-17 YBCV

Ṣugbọn nigbati on o ba yipada si Oluwa, a o mu iboju na kuro. Njẹ Oluwa li Ẹmí na: nibiti Ẹmí Oluwa ba si wà, nibẹ̀ li omnira gbé wà.