II. Kor 3:15-16

II. Kor 3:15-16 YBCV

Ṣugbọn titi di oni oloni, nigbakugba ti a ba nkà Mose, iboju na mbẹ li ọkàn wọn. Ṣugbọn nigbati on o ba yipada si Oluwa, a o mu iboju na kuro.