I. Tim 5:17-18

I. Tim 5:17-18 YBCV

Awọn alàgba ti o ṣe akoso daradara ni ki a kà yẹ si ọlá ilọpo meji, pẹlupẹlu awọn ti o ṣe lãlã ni ọ̀rọ ati ni kikọni. Nitoriti iwe-mimọ́ wipe, Iwọ kò gbọdọ dì malu ti ntẹ̀ ọkà li ẹnu. Ati pe, ọ̀ya alagbaṣe tọ si i.