I. Tim 4:12-13

I. Tim 4:12-13 YBCV

Máṣe jẹ ki ẹnikẹni ki o gàn ewe rẹ; ṣugbọn ki iwọ ki o jẹ apẹrẹ fun awọn ti o gbagbọ́, ninu ọ̀rọ, ninu ìwa hihu, ninu ifẹ, ninu ẹmí, ninu igbagbọ́, ninu ìwa mimọ́. Titi emi o fi de, mã tọju iwe kikà ati igbaniyanju ati ikọ́ni.