I. Tim 2:3-5

I. Tim 2:3-5 YBCV

Nitori eyi dara o si ṣe itẹwọgbà niwaju Ọlọrun Olugbala wa; Ẹniti o nfẹ ki gbogbo enia ni igbala ki nwọn si wá sinu ìmọ otitọ. Nitori Ọlọrun kan ni mbẹ, Onilaja kan pẹlu larin Ọlọrun ati enia, on papa enia, ani Kristi Jesu