I. Tes 3:7-9

I. Tes 3:7-9 YBCV

Nitori eyi, ará, awa ni itunu lori nyin ninu gbogbo wahalà ati ipọnju wa nitori igbagbọ́ nyin: Nitori awa yè nisisiyi, bi ẹnyin ba duro ṣinṣin ninu Oluwa. Nitori ọpẹ́ kili awa le tún ma dá lọwọ Ọlọrun nitori nyin, fun gbogbo ayọ̀ ti awa nyọ̀ nitori nyin niwaju Ọlọrun wa