Bi ọmọ-ọwọ titun, ki ẹ mã fẹ wàra ti Ẹmí na eyiti kò li ẹ̀tan, ki ẹnyin ki o le mã ti ipasẹ rẹ̀ dàgba si igbala
Kà I. Pet 2
Feti si I. Pet 2
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: I. Pet 2:2
3 Awọn ọjọ
Jésù Krístì wá kú fún ẹ̀ṣẹ̀ wa kí a lè ní ìyè àìnípẹ̀kun. Àtúnbí sínú ayé tuntun ni. Nítorí náà ó ṣe pàtàkì pé kí onígbàgbọ́ tuntun ní òye ìhùwàsí, àǹfààní àti àṣà ayé tuntun yìí.
5 Awọn ọjọ
Nípa ìrètí rẹ̀ nínú lẹ́tá tí ó ko sí ìjọ àkọ́kọ́, Peteru gbà wá níyànjú kí a ní ìgbàgbọ́, kí á sì gbọ́ràn. Ó ní kí á dúró sinsin nínú ìgbàgbọ́ nígbà tí a bá ń kojú àdánwò àti inúnibíni. Ó ní nítorí ẹ̀dá tí a jẹ́ nínú Jésù, a ní agbára láti gbé ìgbá ayé ìwà mímọ́, a ó sì le ní àfojúsùn ogún ayérayé.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò