I. Joh 1:3-4

I. Joh 1:3-4 YBCV

Eyiti awa ti ri, ti awa si ti gbọ́ li awa nsọ fun nyin, ki ẹnyin pẹlu ki o le ní ìdapọ pẹlu wa: nitõtọ ìdapọ wa si mbẹ pẹlu Baba, ati pẹlu Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi. Awa si kọwe nkan wọnyi si nyin, ki ayọ̀ nyin ki o le di kikún.