Ẹnyin kò mọ̀ pe awọn alaiṣõtọ kì yio jogún ijọba Ọlọrun? Ki a má tàn nyin jẹ: kì iṣe awọn àgbere, tabi awọn abọriṣa, tabi awọn panṣaga, tabi awọn alailera, tabi awọn ti nfi ọkunrin bà ara wọn jẹ́, Tabi awọn olè, tabi awọn olojukòkoro, tabi awọn ọmuti, tabi awọn ẹlẹgàn, tabi awọn alọnilọwọgbà ni yio jogún ijọba Ọlọrun.
Kà I. Kor 6
Feti si I. Kor 6
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: I. Kor 6:9-10
7 Awọn ọjọ
Àwọn Kristẹni ni wọ́ n ń pè ní ẹ̀ yà ara Kristi; àwọn èèyàn tí wọ́ nfi owórà, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀ -èdè mímọ́ , àwọn ọba àti àlùfáàfúnỌlọ́ run, àwọn èèyàn tí yóò bá Kristi jọba lórí ilẹ̀ ayé, àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ. pẹlu idiyele kan, awọn ibeere pataki kan wa lori wa, ti a pinnulati ṣeiyatọwa lati iyoku gbogbo, pataki ni ọna ti a gbe ni agbaye lọwọlọwọ. Pauluninulẹta rẹ si Ijo Korinti ni lati mu awọn ibeere wọnyi wa si imọlẹ. Ni ọsẹyii, ayoo wo diẹ ninu awọn ibeere wọnyi.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò