I. Kor 16:7-9

I. Kor 16:7-9 YBCV

Nitori emi kò fẹ ri nyin li ọ̀na-ajò nisisiyi; nitori emi nreti ati duro lọdọ nyin nigba diẹ, bi Oluwa ba fẹ. Ṣugbọn emi o duro ni Efesu titi di Pẹntikọsti. Nitoripe ilẹkun nla ati aitase ṣi silẹ fun mi, ọ̀pọlọpọ si li awọn ọtá ti mbẹ.