I. Kor 15:33-34

I. Kor 15:33-34 YBCV

Ki a má tàn nyin jẹ: ẹgbẹ́ buburu bà ìwa rere jẹ. Ẹ jí iji ododo, ki ẹ má si dẹṣẹ̀; nitori awọn ẹlomiran kò ni ìmọ Ọlọrun: mo sọ eyi ki oju ki o le ti nyin.