I. Kor 12:18-20

I. Kor 12:18-20 YBCV

Ṣugbọn nisisiyi Ọlọrun ti fi awọn ẹ̀ya sinu ara, olukuluku wọn gẹgẹ bi o ti wù u. Bi gbogbo wọn ba si jẹ ẹ̀ya kan, nibo li ara iba gbé wà? Ṣugbọn nisisiyi, nwọn jẹ ẹya pupọ, ṣugbọn ara kan.