I. Kor 10:2-4

I. Kor 10:2-4 YBCV

Ti a si baptisi gbogbo wọn si Mose ninu awọsanma ati ninu okun; Ti gbogbo wọn si ti jẹ onjẹ ẹmí kanna; Ti gbogbo wọn si mu ohun mimu ẹmí kanna: nitoripe nwọn nmu ninu Apata ẹmí ti ntọ̀ wọn lẹhin: Kristi si li Apata na.