I. Kro 2:13-17

I. Kro 2:13-17 YBCV

Jesse si bi Eliabu akọbi rẹ̀, ati Abinadabu àtẹle, ati Ṣimma ẹkẹta. Netanneeli ẹkẹrin, Raddai ẹkarun, Osemu ẹkẹfa, Dafidi ekeje: Awọn arabinrin wọn ni Seruiah ati Abigaili. Ati awọn ọmọ Seruiah; Abiṣai, ati Joabu, ati Asaeli, mẹta. Abigaili si bi Amasa: baba Amasa si ni Jeteri ara Iṣmeeli.