ORIN DAFIDI 9:2

ORIN DAFIDI 9:2 YCE

N óo yọ̀, inú mi yóo sì máa dùn nítorí rẹ; n óo kọ orin ìyìn orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.