ORIN DAFIDI 7:1

ORIN DAFIDI 7:1 YCE

OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni mo sá di; gbà mí là, kí o sì yọ mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi.