ORIN DAFIDI 63:2-4

ORIN DAFIDI 63:2-4 YCE

Mo ti ń wò ọ́ ninu ilé mímọ́ rẹ, mo ti rí agbára ati ògo rẹ. Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára ju ìyè lọ, n óo máa yìn ọ́. N óo máa yìn ọ́ títí ayé mi; n óo máa tẹ́wọ́ adura sí ọ.

Àwọn àwòrán ẹsẹ fún ORIN DAFIDI 63:2-4

ORIN DAFIDI 63:2-4 - Mo ti ń wò ọ́ ninu ilé mímọ́ rẹ,
mo ti rí agbára ati ògo rẹ.
Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára ju ìyè lọ,
n óo máa yìn ọ́.
N óo máa yìn ọ́ títí ayé mi;
n óo máa tẹ́wọ́ adura sí ọ.