ORIN DAFIDI 6:2

ORIN DAFIDI 6:2 YCE

Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi, OLUWA, wò mí sàn nítorí ara ń ni mí dé egungun.