ORIN DAFIDI 5:8

ORIN DAFIDI 5:8 YCE

OLUWA, tọ́ mi sọ́nà òdodo rẹ, nítorí àwọn ọ̀tá mi; jẹ́ kí ọ̀nà rẹ hàn kedere níwájú mi.