ORIN DAFIDI 13:1

ORIN DAFIDI 13:1 YCE

Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni? Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi?