ORIN DAFIDI 127:3-4

ORIN DAFIDI 127:3-4 YCE

Wò ó! Ẹ̀bùn OLUWA ni ọmọ; òun ní fi oyún inú ṣìkẹ́ eniyan. Bí ọfà ti rí lọ́wọ́ jagunjagun, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ìgbà òwúrọ̀ ẹni.