ORIN DAFIDI 125:1

ORIN DAFIDI 125:1 YCE

Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWA dàbí òkè Sioni, tí ẹnikẹ́ni kò lè ṣí nídìí, ṣugbọn tí ó wà títí lae.