ORIN DAFIDI 112:5

ORIN DAFIDI 112:5 YCE

Yóo máa dára fún ẹni tí ó bá lójú àánú, tí ó sì ń yáni ní nǹkan, tí ó ń ṣe ẹ̀tọ́ ní gbogbo ọ̀nà.