ÌWÉ ÒWE 30:17

ÌWÉ ÒWE 30:17 YCE

Ẹni tí ń fi baba rẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́, tí ó kọ̀ tí kò tẹríba fún ìyá rẹ̀, ẹyẹ ìwò àfonífojì ati àwọn igún ni yóo yọ ojú rẹ̀ jẹ.