ÌWÉ ÒWE 3:28

ÌWÉ ÒWE 3:28 YCE

Má sọ fún aládùúgbò rẹ pé, “Máa lọ ná, n óo fún ọ tí o bá pada wá lọ́la,” nígbà tí ohun tí ó fẹ́ wà lọ́dọ̀ rẹ.