ÌWÉ ÒWE 26:1-2

ÌWÉ ÒWE 26:1-2 YCE

Bí yìnyín kò ṣe yẹ ní àkókò ooru, ati òjò ní àkókò ìkórè, bẹ́ẹ̀ ni iyì kò yẹ òmùgọ̀. Bí ológoṣẹ́ tí ń rábàbà kiri, ati bí alápàáǹdẹ̀dẹ̀ tí ń fò ká, bẹ́ẹ̀ ni èpè tí kò nídìí, kì í balẹ̀ síbìkan.