ÌWÉ ÒWE 2:6

ÌWÉ ÒWE 2:6 YCE

Nítorí OLUWA níí fún ni ní ọgbọ́n, ẹnu rẹ̀ sì ni òye ati ìmọ̀ ti ń wá.