ÌWÉ ÒWE 15:29-30

ÌWÉ ÒWE 15:29-30 YCE

OLUWA jìnnà sí eniyan burúkú, ṣugbọn a máa gbọ́ adura olódodo. Ọ̀yàyà a máa mú inú dùn, ìròyìn ayọ̀ a sì máa mú ara yá.