ÌWÉ ÒWE 13:3

ÌWÉ ÒWE 13:3 YCE

Ẹni tí ó ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀, ẹ̀mí ara rẹ̀ ni ó ń ṣọ́, ẹni tí ń sọ̀rọ̀ àsọjù yóo parun.