MAKU 9:41

MAKU 9:41 YCE

Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá fun yín ní omi mu nítorí tèmi, nítorí pé ẹ jẹ́ ti Kristi, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé yóo rí èrè rẹ̀ gbà.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ