MATIU 19:14

MATIU 19:14 YCE

Ṣugbọn Jesu sọ pé, “Ẹ jẹ́ kí àwọn ọmọde wá sọ́dọ̀ mi; ẹ má dí wọn lọ́nà, nítorí ti irú wọn ni ìjọba ọ̀run.”

Àwọn fídíò fún MATIU 19:14