MATIU 16:25

MATIU 16:25 YCE

Nítorí ẹni tí ó bá fẹ́ gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là yóo pàdánù rẹ̀. Ṣugbọn ẹni tí ó bá pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ nítorí mi, yóo rí i.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ