ẸKÚN JEREMAYA 5:21

ẸKÚN JEREMAYA 5:21 YCE

Mú wa pada sọ́dọ̀ ara rẹ, OLUWA, kí á lè pada sí ipò wa. Mú àwọn ọjọ́ àtijọ́ wa pada.