JUDA 1:1-2

JUDA 1:1-2 YCE

Èmi Juda, iranṣẹ Jesu Kristi, tí mo jẹ́ arakunrin Jakọbu ni mò ń kọ ìwé yìí sí àwọn tí Ọlọrun Baba fẹ́ràn, tí Jesu Kristi pè láti pamọ́. Kí àánú, alaafia ati ìfẹ́ kí ó máa pọ̀ sí i fun yín.